Ko
si orin meji tawon to ja si orin taka-sufe (hiphop) tun n gbo bayii, bi ko se
eyi ti won pe ni Perfect Woman, iye Obinrin To Pe.
Okan
lara awon irawo olorin to sese n dide bo l’orileede Naijiria lo ko orin naa
lati fi gboriyin fawon obinrin wa. Orin to ko awon eeyan lekoo repete ni.
Awon
to ba gbo o nikan lo le ye; Awon ibi ti e ti le rii gbo (download) ni won yii;
Bakan naa ni orin min in ti won pe ni Bojan
- Cypher naa tun jade pelu e; eyi lawon ibi ti e ti le rii download
NaijaSureGuys: http://naijasureguys.com.ng/download-music-bojan-cypher/
InAndoutent: http://www.inandoutent.com/music-bojan-cypher/
GrooveNaija360: https://groovenaija360.com.ng/music-bojan-cypher/
Davido – A Good Time Album https://trendsfox.ng/davido-a-good-time-album/
ReplyDelete