Gomina
ipinle Ogun, Ibikunle Amosun ti fowo soya seleri wi pe oun yoo ri daju wi pe
gbogbo eto to ba to sawon ijoba ibile ati idagbasoke ti won sese da sile loun
yoo fun won lati mu ki ise won yo.
Amosun
soro yi lakoko to n soro nibi ipade eto isuna owo odun 2018 to waye nile igbimo
asofin ipinle naa.
O
so pe kii se aheso tabi iro wi pe awon ijoba idagbasoke metadinlogoji ti win da
sile lodun to koja je pataki ibi ti owo ti n wole sapo ijoba ipinle naa, ati pe
awon gan an lo je kawon araalu tun sunmo ijoba daadaa.
Amosun
ni o di dandan kawon wa ona lati je kawon naa da duro, ki won ma si maa duro de
ijoba ki won to k sohunkohun.
Bakan
naa lo tun je ko ye awon eeyan wi pe latari wahala ipo oye to n sele nipinle
naa, ijoba ti se tan lati bere ileejo Tribunal ti yoo maa gbo ejo won lati ba
won yanju aawo to ba n sele.
No comments:
Post a Comment