Titi
di bi a ti n sakojopo iroyin, inu ibanuje nla ni Asiwaju egbe oselu All
Progressives Congress, APC, eni to tun je Gomina ipinle Eko tele, Asiwaju Bola Ahmed
Tinubu atawon ebi e wa bayii lori bi won se padanu omo won, Jide lojiji.
Tinubu, Oloogbe Jide ati Mama e |
Gege
bi iroyin to te AWIKONKO lowo lati odo alaga egbe oselu naa nipinle Eko, Otunba
Henry Oladele Ajomale nirole oni, o so pe ibanuje nla niku naa fawon ebi Tinubu
lasiko yii.
Jide
Tinubu la gbo pe odun 1999 ni won pe sinu egbe amofin orileede yi, iyen Nigerian
Bar, to si lo si fasiti Liverpool lorileeede England nibi to ti ni iwe eri
Masters ninu eko ofin Maritime.
Bo tile je pe a ko tii le so pato nipa ohun to sokunfa ilu Jide Tinubu titi ta a fi sakojopo iroyin yi tan, sugbon a fi n da yin lo ju pe ekunrere iroyin naa n bo lai pe, e ku oju lona
No comments:
Post a Comment