Bi a ba n so nipa
awon ileese to duro deede, tawon ojogbon kaakiri agbaye fowo e soya pe awon gan
an lo ye ki won maa pe ni asaaju onisowo nile Adulawo, iyen Afrika nitori awon
ipa rere ti won ti ko nigbesi aye awon eeyan.
Odu ni ileese Balocool Excel Nigeria Limited to je pe
awon ero amunkan tutu, firiiji (fridge & freezer) ni won yan laayo lati maa
fi sawon araalu lanfaani, kii saimo foloko. Opo awon eeyan ni won si ti je
anfaani alailegbe tileese to ti le ni ogun odun naa gbekale.
E waa gbo o, ki
AWIKONKO to lee gbe ileese Balocool,
to je ti gbajumo onisowo nni, Alaaji Adelusi Balogun Shittu sita faraye, o ye
ki e ti mo pe o ni bo se je, a wa kii tori owo gbe eeyan tabi polowo oja sita
fawon araalu, nitori pe itiju nla ni yoo je fun iwe iroyin wa lati maa gbe awon
ayederu ileese sita.
Balocool pelu awoodu |
Opo ami eye ni
ileese Balocool ti gba lorileede yi
ati lawon orileede bii Ghana, Burkina Faso, South Africa, Tunisia atawon mi in.
Ko lo n ka lawon emi eye awoodu ti ileese Balocool
ti gba nibi awon ipate ita gbangba apapo lorileede yi, bi Abuja International Trade Fair,
Calabar International Trade Fair, Osun Trade Fair, Kaduna Trade Fair, Lagos International Trade Fair abbl.
Anfaani alailegbe lo
ti wa a wa nile bayii ti ileese naa ti ko de fawon eeyan to ba fee saseyori
laye, ti won si fe maa je ere repete lori awon oja ti won ba ra.
Ileese Balocool lo n se awon ohun amunkan tutu,
ti yoo tun di bulooku. Awon oja won ni Deep Freezer ti won fi n yo bulooku,
Fridge lorisirisi ni won ta, ati pe yato si pe won n ta a, won tun n bawon tun
un se to ba yonu.
Owo won ko han pupo,
bee lawon bulooku to ba yo le lo ojo marun ko too di omi pada, awon olode ariya
ni won le so. Ko sibi ti e wa lorileede yi, tabi nile Afrika ti won ti kii n wa
ra oja won.
Ofiisi won tuntun |
Edinwo idamarun tun
ti wa lori awon oja won bayii, bee lo si je pe anfaani osu mefa gbako ti wa
nile ti awon oja yin ba yonu, lati baa yin paaro e.
Bi e ba fee kan si
won, oluuleese won wa ni; No. 5, Balocool Building, Olorunsogo Street, Palace
Road, Ofatedo Osogbo, Osun State.
Eka ileese won tun
wa ni;
Lagos
Office: 703, Opposite Ijaye Bus-Stop, Abeokuta Express
Road, Lagos.
Abuja
Office: Second Line, Shop 92, Civic Centre, G/L, Abuja.
Awon ero ibanisoro
won ni: 08034442119, 08033586735,
08057989352.
No comments:
Post a Comment