Oba Ogunwusi |
Oba Adeyeye
Ogunwusi, Ooni Ile-Ife ti so pe ko seni to le si Aare Muhammadu Buhari nipo
lodun 2019 bi ko se awon odo orileede yi, nitori owo won gan an ni agbara
Naijiria wa.
Oba Ogunwusi so pe
awon odo ko mo pe awon gan an ni agbara wa lowo e ninu gbogbo nnkan to n lo
lorileede yi. O ni bi won ba ro pe isejoba Buhari ko te awon lorun, ki won fi
ibo won le danu kuro gege bi Aare.
Kabiyesi ni kawon
odo yee pariwo kaakiri pe isejoba yi dara, ki won yee saniyan mo, nitori pe won
ni agbara lati yan eni ti won ba fe sipo. Bee lo gbawon nimoran pe ki won yee
fi oro ikorira orileede yi sita mo.
Ninu oro ti Ooni fi
sita lo tun ti so pe bawon odo ba mo pe agbara wa lowo won nipa idibo ni, won
ko ni yee pariwo mo.
No comments:
Post a Comment