Kayeefi loro oko atiyawo Mathew Abioro ati Precious Oyekunle
Abioro tasiri won tu sawon olopaa lowo lojoru Wesde ose to koja lagbegbe Sango
lakoko ti won tun fee lo pawon eeyan lekun gege bi won ni won se n ma n se.
Matthew ati Iyawo e |
Gbara ti won lawon FSARS ti gbo ni won ti gbera lati loo
koju won ti won si ri won nibi ti won maa n sapamo si ki won too sise, ati
leyin ti won ba sise won tan.
“E se wa jeje” ni won loro ebe to n jade lenu won ko too dip
e won ko won de olu ile ise olopaa to wa ni Eleweran lati tub o gboro lenu won
lori bi won se n sise ibi won.
Mathew ati Precious nigba tawon olopaa n foro wa won lenu wo
so pe looto lawon ti n jale tawon si ti n lu jibiti tipe, sugbon oro atije lo
sun awon debi iwa adojutini naa. Won ni Kutonu,
Orileede Benin lawon maa n ta eru
tawon ba ji si, ki asiri ma baa tu.
Siwaju sii ni Precious so pe okada tawon ole gba ja gba, ti
won bag be fun awon, orileede Benin lawon maa ta si tawon si ma fi n ra irinse
bii ibon tawon maa n lo lati fi sise.
Agbenuso olopaa, Abimbola Oyeyemi nigba to n soro naa
fakoroyin wa nirole ojo Abameta Satide so pe Orisirisi ibon at iota lawon ri
gba lowo won, sugbon Oga awon, Ahmed Iliyasu ti so pe ki won tubo tea won eeyan
naa ninu daadaa, ki won sir ii pe won jewo awon ti won jo n sise.
Iliyasu so pe bo tile je pea won mejeeji naa ko ni pe e foju
bale ejo, sibe oun ko ni fi aaye gba awon to odaran to ba n gbero lati da
alaafia awon araalu laamu.
No comments:
Post a Comment