Omodo Agba |
Agba ogbontairigi sorosoro nni nipinle
Ogun, Alaaji Moruph Adegboye, tawon eeyan mo si Omodo-Agba ti so pe kii se pe
oun muti yo lojo ti Oloye Adeifa Sogbeinde sayeye odun ifa olodoodun to maa n
se, eyi to waye logbon ojo osu to koja nilu Abeokuta.
Omodo Agba soro yi lakoko to n ba
AWIKONKO soro lojo aje Monde to lo lohun ni ogba olopaa to wa ni Eleweran
Abeokuta lakoko tawon olopaa n foju awon odaran han fawon oniroyin.
O so pe gbogbo igba ti inu oun ba n dun
loun maa n se bebe fawon eeyan paapaa awon to sunmo oun lakoko ti won ko ba
lero. O ni wipe oun ko maa n na owo loju agbo ti a so yen, kii se ooto nitori
pe oun ko le se koun ma na owo.
Bakanna lo so siwaju pe iwa rere leso
omo eniyan laye, nitori e lo se je pe o dara ki eeyan maa se daadaa ni gbogbo
igba, atipe ojo iwaju lo ye ki eda maa ro laye.
No comments:
Post a Comment