Ibeere tawon eeyan n
beere ni pe ki lo wa laarin awon gbajumo sorosoro to je omo egbe FIBAN mejeeji
nni, Queen Toyin Adeniji, Olori ati Muibat Oseni, iyen Arewa.
Arewa ati Olori |
Bo tile je pe ko
seni to le so pato nnkan to wa laarin awon mejeeji sugbon nkan to je ki won maa
beere ibeere naa ni bo se je pe ibi ti won ba ti ri Olori naa ni won ti maa ri Arewa.
Yato si wipe awon mejeeji je sorosoro lobinrin, won ni nnkan min in tun pa won po to yato si ise redio, ohun lo se je pe lojo ti Arewa se ojoobi e laipe yi, Olori lo n se kukukeke, to n gbawaju gbeyin bi eni pe won je omo iya.
Yato si wipe awon mejeeji je sorosoro lobinrin, won ni nnkan min in tun pa won po to yato si ise redio, ohun lo se je pe lojo ti Arewa se ojoobi e laipe yi, Olori lo n se kukukeke, to n gbawaju gbeyin bi eni pe won je omo iya.
Bi e ba si ti ri
obinrin meji ti won jo n se wole wode ni gbogbo igba, o ni lati je pe oro asiri
kan wa laarin won ni, atipe gbeborun lo maa n saba wa ninu oro awon obinrin, ti
won ko si fe ki enikeni mo idi abajo to wa laarin won, nitori pe bi e ba bi
awon mejeeji pe ki lo n sele, ko si nkankan ni won maa so.
Fun eni to ba ri
awon mejeeji ti e wo aworan won yi, bo ya e le ba wa beere pe ki lo wa laarin
won ti ajosepo won fid an monran to bee.
Ko kuku seni ti
AWIKONKO ko le gbe oro e jade sita. Sugbon sa o, adura AWIKONKO nipe gbogbo eni
to ba fee da aarin awon mejeeji ru ni Oba oke maa da ona e ru. Iko kii ko omo
ejo lese, gbogbo ibi ti e ba n gba ni Adedaa yoo maa tele yin.
No comments:
Post a Comment