Ayo abara tintin
loro naa bayi ninu idile gbajumo agbefiimu jade nni, Seun Egbegbe nitori pe
iyawo e to sese bimo tuntun jojolo.
Seun Egbegbe re e |
Bo tile je pe Seun
Egbegbe si wa latimole awon olopaa to wa ni Kirikiri nilu Eko titi di asiko yi
lori esun ole jija ti won fi kan laarin osu meji sira won, to si ti foju bale
ejo, sugbon ti ko ri eni to le duro fun leyin ti adajo so pe oun fun ni anfaani
pe ki won gba beeli e.
Idi ti ko fi seni to
le duro fun Seun Egbegbe nipe, won beru ki okunrin na ma tun lo jale leeketa,
toripe leyin ti mu lakoko ti won si gba beeli e, ko ju osu kan aabo lo to tun
lo jale miran, eyi lo fat awon eeyan fi sa seyin pe ki Seun ma tun lo doju ti
awon.
Sugbon ni bayii,
AWIKONKO gbo pe inu ironu nla lokunrin naa si wa bayii latigba to ti gbo pe
iyawo ti bimo obinrin lantilanti.
Onyenike to je okan
lara awon orebinrin Seun Egbegbe lo gbe foto omo tuntun naa sori ero ayelujara
Instagram laipe yi lati je ki awon eeyan mo pe oun ti bimo tuntun. Inu oyun ni Onyenike
wa lakoko ti won fesun ole jija kan oko
e ti pada bimo.
Bi e o ba gbagbe,
ojo keta osu to koja, April lo je eleeketa ti Seun Egbegbe foju bale ejo, igba
naa lo si ti foju bale ejo gbeyin, sugbon to tun n reti ojo igbejo miran laipe.
No comments:
Post a Comment