Ojogbon Oyewole ati Ojogbon Daramola |
Lojobo
Tosde ose to koja yi ni atejade kan jade lati odo ijoba apapo, iyen lodo ajo to
n ri soro eko nileewe giga, ti Mallam Adamu Adamu je oga agba e, wipe oun da
awon giwa agba ileeko fasiti Federal University of Technology, FUTA, Ojogbon Adebiyi
Daramola ati Ojogbon Olusola Oyewole ti Federal University of Agriculture,
Abeokuta, FUNAAB duro.
Bo
tile je pe ohun ti agbenuso ile eko Fasiti FUNAAB so ninu atejade to fi sita
fawon akoroyin ni pe, awon ko tii le so boya looto niroyin naa, nitori pe awon
ti bere igbese lati sewadi boya looto niroyin naa.
Sugbon
ninu atejade ti Dokita Hussaini Adamu, to je akowe agba fidihe ni ileese to n
ri si eto eko lorileede yi, iyen Federal Ministry of Education fowo si lo ti so
pe ijoba apapo dawon eeyan naa duro latari ejo ti won n je lowo nile ejo pelu
ajo to n ri si sise owo ilu mokumoku, iyen ajo EFCC.
Ninu
e ni won ti so pe kawon oga agba mejeeji naa ko gbogbo eru to wa nikawo won
fawon to tun je gege bi oga lawon ileeko naa, ki ise si maa lo bo se n lo.
AWIKONKO gbo pe, bawon
osise atawon akekoo ile eko FUTA se gbo iroyin yi, ilu ni won lo o gbe, ti won sib
ere sii korin kaakiri inu ogba wipe awon ti reyin ota won, ti ko je kawon
gbadun latigba ti won ti gbe de be.
No comments:
Post a Comment