Minisita foro oko
ofurufu lorileede yi, Ogbeni Femi Fani-Kayode lo tun ti foju bale ejo bayi lori
esun sise owo ilu mokumoku ti ajo to n ri soro naa, EFCC fi kan lodun to koja.
Owo to to bilionu
marun (N4.9bn) naira lowo naa ti ajo EFCC fi kan an wipe ko wa so tenu e lori
bowo naa se poora.
Iwaju onidajo
tuntun, Rilwan Aikawa lo ti foju han, leyin to so pe oun ko le duro niwaju
adajo to n gbejo naa tele, iyen Onidajo Muslim Hassan to ti koko duro niwaju e
rojo lojo kejidinlogbon osu kefa odun to koja.
No comments:
Post a Comment