Bi ipalemo isinku agba osere nni, Oloogbe Omoba Samuel Adesina Adesanya, Pasito Ajidara ti n sunmo etile, iyen ayeye ti yoo bere l'Ojoru Wesde ose to m bo, ojo kerinlelogun osu yii, Egbe osere Theater and Arts Practitioner
Association of Nigeria, TAMPAN ti gbe oruko awon igbimo ti yoo sagbeteru ayeye isinku
Gomina won sita
fawon eeyan lati mo awon ti won yoo pe bi won ba fee bere ohunkohun nipa bi eto
isinku yoo se lo.
Ninu atejade ti okan lara awon omo egbe naa,
Ogbeni Olusegun Agbaakin Akinwunmi fi sori ero ayelujara laipe yi lo ti safihan
awon merinla naa, pelu awon meji miran, to fi je merindinlogun.
Awon
merinla naa ni;
Otunba Bolaji Amusan, Mista Latin – Alaga
Otunba Bolaji Amusan, Mista Latin – Alaga
Simon Oguntola – akowe
Segun Adesegun - Akapo
Isiaka Ogunnumesi
Yemi Adegunju
Adeleke Adetutu, Seyi Crown
Yinka Adebanjo
Alaaji Lateef Dehinde
Owolabi Ajasa
Olaleye Nathaniel
Bola Odunuga
Folasade Oludele
Yomi Fash-Lanso
Awon
meji miran lori eto iroyin ni;
Gbenga Edun ati
Solaja Oluwafemi
No comments:
Post a Comment