Eleko
tilu Eko, Oba Rilwan Akiolu ti rawo ebe sawon omo orileede Naijiria wi pe ki
won yee ba awon won ja lori oro awon oloselu nitori pe awon gan an lo n da
orileede yi ru.
Oba Akiolu |
Oba
Akiolu soro yi lojo Isegun Tusde to koja yi nibi ayeye ogota odun ti arabinrin
Folashade Asafa, eni to je iyawo senato to n soju ekun ila oorun nilu Ekoo nile
igbimo asofin agba l’Abuja, Senato Gbenga Ashafa.
O
so pe opo awon oloselu lo je pe o nibi ti won ti ma n pade lati yanju oro aarin
ara won, tawon araalu tabi awon ololufee won ko si nii mo, ti won a fi maa ba
ara won ja nigboro.
O
ni eyin ilekun ni won ti n pari oro ju, eyi ko bo ju mu to fawon araalu lati
maa ba ara won yan odi, tabi ni ara won sinu nitori ipo ose laarin awon ololufe
e won.
Lara
awon to wa nibi ayeye to wa ni gbongan Grand View to wa ni Magodo nilu Eko lojo
naa ni Senato Bukola Saraki; Igbakeji Olori awo osise lorileede yi, Ogbeni
Gbenga Makanjuola; Minisita foro ina, opopona ati ile gbigbe, Babatunde
Fashola; Senato Musiliu Obanikoro atawon mi in.
No comments:
Post a Comment