Awon afurasi Fulani
agbebon kan ni won ti fesun kan won pe won sekupa awon agbe to to ogun mo inu
mosalasi ti won ti n kirun laaro ojo Abameta Satide to koja yi.
awon Fulani darandaran |
AWIKONKO gbo pe
abule kan ti won pe ni Etogi nipinle Niger ni won nisele naa ti waye, nigba ti
won so pe se lawon Fulani naa dabon won bole, ti won si gbogbo awon agbe ogun
to n kirun lowo, gege bi Agbenuso awon olopaa ipinle naa, Bala Elkana se so.
Bala tesiwaju pe se
lawon odaran naa tun yinbon kaakiri abule naa, ti won si se awon mejo miran
lese pelu ibon won.
AWIKONKO ninu iwadi
fi han daju pea won Fulani naa ko deede pawon eeyan naa, ohun to faa ni pe se
ni won so pe won wa gbesan okan lara won tawon agbe naa pa laipe yii ni.
No comments:
Post a Comment