Oruko ti
baba ati iya e so ni: Ebenezer Remilekun Aremu Olasupo Obey-Fabiyi.
Nigba
to wa ni kekere ni iya e ti maa n gbe lo si soosi, to si je pe to ba ti gbe
sile pe ko sere, ibi tawon akorin n joko si lo maa ra lo, to si ma lo maa da
awon irinse ti won n lo ru. Bo se n dagba lo n laju si orin, to si darapo mo
egbe akorin ni ile iwe Methodist to wa ni Idogo, iyen nijoba ibile Yewa South
nibi to ti ka ileeko alakobere.
Yato
si wipe o wa ninu egbe akorin nile iwe, o tun wa ninu egbe akorin ninu ijo to n
lo nigba naa. Lakoko naa lo n jinle si ninu ise orin to si je pe awon ala to n
la nigba naa, bi yoo se dagba ninu ise orin kiko ni.
Ebenezer
Obey Fabiyi ni won fi se adari egbe olorin kan tawon odo nilu Idogo da sile,
eyi ti won pe ni Ifelodun Mambo Orchestra. Leyin naa loun naa da egbe ti
e sile lodun 1957, egbe naa lo pe ni Royal Mambo Orchestra. Ko pe to da
egbe yi sile lo ko gbogbo irinse e, to si gba ilu Eko lo.
Gbajumo
olorin kan naa wa nigba naa Taye n gba ti e, Adeolu Akinsanya loruko e,
orin juju lo n ko. Orin e wa lara awon orin ti Ebenezer Obey n gbo to si ma n
wu lori. Eyi lo je koun naa maa wo awokose baba naa, to si bere sii korin bii
ti e, sugbon, ko geeti e daadaa, eyi lo mu pinu lati sunmo Alagba Akinsanya
yii lati le ko eko siwaju sii nipa orin. Baba yi lo tubo ran lowo lati le se
aseyori siwaju si ninu ise orin to yan laayo.
Nigba
to to asiko kan, loun naa wo pe ona wo loun tun le gba lati mu ki orin toun
yato si awon orin juju toku, eyi lo muu ronu lati gba ona ara miran yo sawon
eeyan paapaa awon ololufe e atawon ti won jo n figagbaga, to si mu MILIKI
wonu e.
Nigba
to ya lo tun tesiwaju lati darapo mo egbe olorin ti Oloogbe Fatai Rolling
Dollar da sile, ko too tun da egbe miran sile to pe ni The
International Brothers, iyen lodun 1964 nibi to ti n play
highlife fun won. Sugbon lodun 1970 lo tun gbe egbe naa goke agba to si yi
oruko e pada si Inter-Reformer. Oruko egbe yi lo fi se awon orin jade to kun
fun opolopo track to si mile Afrika titi, bee ni won tun fun ni West African
Decca musical label.
Ilu,
gita ati gangan to fi kun orin e lo je kawon to gbo Faaji feran lati maa gbo
orin e, ki won si maa milengbe. Odun 1990s lo feyinti ninu ise orin to n ko
tele, ko too di pe Olorun pe, o si n korin igbagbo.
Yato
si wipe Oloye Ebenezer padanu akaimoye awon awo orin to ti se atawon eyi to fee
gbe jade nibi ijamba ina kan to jo ile ise e, iyen DeCross lodun 1995,
sibe, ko lonka lawon orin e to si wa di asiko yi taye si n gba ti e.
LARA
AWON ORIN TO TI GBE JADE NI:
1964
- Ewa Wo Ohun Ojuri
1965
- Aiye Gba Jeje b/w Ifelodun - Gari Ti Won b/w Orin Adura
1966
- Awolowo Babawa Tide b/w Oluwa Niagbara Emi Mi*Palongo b/w Teti Ko Gboro
Kan*Oro Miko Lenso b/w Orin Ajinde*Late Justice Olumide Omololu b/w Iyawo Ti Mo
Ko Fe
1967
- Olomi Gbo Temi b/w Maria Odeku*To Keep Nigeria One b/w Awa Sope Odun
Titun*Edumare Lon Pese b/w Omo Olomo*Ope Fun Oluwa b/w Paulina
1968
- Ore Mi E Si Pelepele b/w Ajo Ni Mo wa*Ijebu L'ade b/w Lati Owolabi*Col. Ben
Adekunle b/w Ori Bayemi*Lolade Wilkey b/w Adetunji Adeyi*Gbe Bemi Oluwa b/w
Olowo Laiye Mo
1969
- Ode To Nso Eledumare b/w Pegan Pegan*Sanu-olu b/w K'Oluwa So Pade Wa*London
Lawa Yi b/w Oro Seniwo*Isokan Nigeria / etc.*Eni Mayo Ayo / etc1969/1970*Emi
Yio Gbe Oluwa Ga b/w Ise Teni
1970
- Lawyer Adewuyi*Ala Taja Bala b/w Ohun Toluwa Ose*Ogun Pari / etc.*In
London*On The Town
1971
Ija Pari (Part One) b/w Ija Pari (Part Two)*Esa Ma Miliki b/w Awon Alhaji*Face
to Face b/w Late Rex Lawson*Oro Nipa Lace b/w Yaro Malaika
1972
Late Oba Gbadelo II*Board Members*Vol.4: Aiye Wa A Toro*In London Vol. 3*Odun
Keresimesi
1973
And His Miliki Sound*The Horse, The Man and His Son*E Je Ka Gbo
T'Oluwa*Adeventure of Mr. Music*Mo Tun Gbe De
1974
Inter-Reformers A Tunde*Eko Ila*Around the World*Iwa lka Ko Pe
1975
Mukulu Muke Maa Jo*Ota Mi Dehin Lehin Mi*Alo Mi Alo*Edumare Dari Jiwon
1976
Late Great Murtara Murtala Ramat Muhammed*Operation Feed The Nation
1977
Eda To Mose Okunkun*Immortal Sings for Travellers*Adam and Eve
1978
Igba Owuro Lawa*Oluwa Ni Olusa Aguntan Mi*No Place Be Like My Country Nigeria
1979
In the Sixties Vol.1*In the Sixties Vol.2*Igba Laiye*Sky*E Wa Kiye Soro Mi*Omo
Mi Gbo Temi
1980
Leave Everything to God*Current Affairs*Sound of the Moment*Eyi Yato
1981
Joy of Salvation*What God Has Joined Together
1982
Celebration*Austerity*Precious Gift
1983
Ambition*Singing for the People*Greatest Hits Vol. 3*Je Ka Jo*Thank You (Ose)
1984
The Only Condition to Save Nigeria*Solution*Peace1985*Security*My Vision
1986
Gbeja Mi Eledumare*Satisfaction*Providence
1987
Aimasiko*Immortality*Victory*Patience
1988
Determination*Vanity
1989 Formula 0-1-0*Get Yer Jujus Out
1989 Formula 0-1-0*Get Yer Jujus Out
1990
Count Your Blessing*On the Rocket
1991 Womanhood
1991 Womanhood
1993
Good News
1994 I Am a Winner*Walking Over (1994 ?)
1994 I Am a Winner*Walking Over (1994 ?)
1995
The
Legend
1999 Millennial Blessings
1999 Millennial Blessings
2000
Promised
Land
2002 Ase Oluwa
2002 Ase Oluwa
Aimasiko
2006
The Horse, The Man & ... 2006
The Horse, The Man & ... 2006
Gbebe
Mi Oluwa 2006
Oro Seniwo 2012
Oro Seniwo 2012
Iba
F'Oluwa/Ajokodabi ...
2012
Ori Mi Koni Buru 2006
Ori Mi Koni Buru 2006
Ota
Mi Dehin
2006
Anjade Loni Eledumare 2006
Anjade Loni Eledumare 2006
Baba
Loran Mi Wa 2012
LARA
AWON OLORIN TI WON JO N FIGAGBAGA LODUN NAA LOHUN
King
Sunny Adé
Shina
Peters
Orlando
Owoh
Onyeka
Onwenu
Victor
Uwaifo
Sonny
Okosun
Chief
Stephen Osita Osadebe
Victor
Olaiya
No comments:
Post a Comment