"E pa wa sile, e ma pa wa sita" loro to n jade
lenu Joseph David ati Adebayo Olanrewaju ni tesan olopaa, Eleweran Abeokuta lojobo
Tosde ose to koja leyin tasiri won tu.
Joseph ati Adebayo |
Gege bi AWIKONKO se gbo, agbegbe Agbado lowo ti te won pelu
aso soja ti won fi n lu awon araalu ni jibiti owo ati eru orisirisi.
Won lawon odaran naa ko fawon ara agbegbe naa lokan bale rara, nitori aso soja ti won fi n boju sise ibi won.
Nigba ti isu maa dile leyin asunsuje won losan Ojobo Tosde
naa, won lawon lokunrin meji ti won na, ti won si se lese lo lo fejo sun awon
olopaa pe awon soja kan ti sise se.
Ogbeni Paul Oniyo ti won lagbofinro ni ati Chima Solomon ni
won loo so fawon olopaa Agbado pe awon eeyan naa fi iya he awon lona ti ko
bofin mu.
Loju ese ni won ni DPO ekun naa, Ogbeni Abioye Shittu ko
awon olopaa soko lati lo mo nnkan to n sele, sugbon won ni se lawon eeyan naa n
gbon lohun nigba ti won ri awon olopaa, eyi lo mu ki DPO naa ko won lo si tesan
lati lo foro wa won lenu wo.
Nigba ti won de tesan lasiri won tu sawon olopaa lowo pe
ogberi ni won, won kii sawo awon soja. Lesekese ni Komisana olopaa, Ahmed
Iliyasu ti pase pe ji won maa kp won bo ni Eleweran, nibi ti won ti n ka bi eye
ayekooto.
Abimbola Oyeyemi nigba to n soro so pe iwadi si n lo lowo
lori awon ise ibi ti won ti se seyin. O ni awon eru soja lpris
O so pe bo tile je pe Komisana won ti pase pe kawon SCIID
tesiwaju ninu oro won, sugbon leyin iwadi, o see se ki won foju bale ejo.
No comments:
Post a Comment