Iroyin to n lo kaakiri agbaye bayii ni ti ayeye odun Festac77 ti won ni awon orileede nile Afrika to le ni marundinlaadota ni won fee kopa lati se ayeye naa.
Gege bi
AWIKONKO se gbo, ojo kinni osu kerin ni ayeye naa yoo bere kaakiri ile adulawo
pelu awon eto aramanda olokan-o-jokan ti won ni won ti la sile fun ayeye naa.
Dokita
Ferdinand Anikwe to je alakoso agba ajo Centre
for Black Arts and Africa Civilization, CBAAC, lo soro yi lakoko to n bawon
oniroyin soro niluu Ekoo lojo Aiku Sande to koja yii.
No comments:
Post a Comment