Emi ni mo lowo ju lagbaye – Pasito Adeboye - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Friday, January 20, 2017

Emi ni mo lowo ju lagbaye – Pasito Adeboye


Pasito Adeboye



Olori ijo Irapada, The Redeemed Christian Church of God, RCCG lagbaye, Pasito Enoch Adejare Adeboye ti so pe oun loun lowo julo lagbaye, “Mo lowo ju Bill Gates lo. Orileede to fee to igba, 200 ni mo ni ile si.”

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI