Nje e ti
gbo nipa okunrin kan ti won n pe Alabi Okunmase?
Omo bibi
Isaga Orile ni Yewa, ipinle Ogun State ni.
Okunrin naa
ti n gbe nilu Abeokuta ojo ti pe, ko da, ile ti ta sii, eyi to ki okunrin naa
gbo ede Egba gidi gan, ko daa ju awon ti won pe ara won ni omo Egba naa lo.
Ko ka iwe
pupo, nitori pe, ko mo iwe, bee ko feeli ri. Aarin meji lo wa.
Lakoko to n
sise ijoba, anfaani tun si sile fun lati maa wa oko taisin (taxi) lati maa fi
pawoda, ki o si maa ri owo die die lati maa fi bo ebi e.
Alabi
Okunmase tera mo oko taisin e gidi leyin to feyinti nidi ise ijoba. Opo awon
eeyan ni won kii fe ko maa gbe won nitori oro ti kii tete ye, to si je pe ejo
lo maa n ro kaka ko koju sibi to ba n lo.
Oro kii
tete ye Alabi nitori iwe ti ko ka, eyi maa n je ko pada awon ero to ba ye ko
gbe lati fi pa owo wole. Ti e ba fee mo nipa Alabi Okunmase, a fi ki maa ba
itan e lo lori YouTube OMOBA TV lojoojo
Tosde.
Ojobo Tosde
ose-ose ni fiimu awoowotan apanilerin Alabi Okunmase maa jade sita fawon eeyan
lati wo.
E le rii wo
lori YouTube: Omoba TV
E tun le
rii wo lori;
Facebook: www.fb.com/omoba-tv
Twitter: www.twitter.com/omoba-tv
Whatsapp:
+2348032370756
No comments:
Post a Comment