Louis |
Gege
bi AWIKONKO se gbo, won ni iya okan lara awon omo ti baba agbaya naa fipa ja
ibale e lo lo so fawon olopaa lojobo Tosde ose to koja lati wa fi owo ofin muu.
Won
so pe obinrin naa leyin to sakiyesi isesi omo e, to je odun mejo pe ayipada kan
ti de si lara, lo beere pe ki lo sele sii.
Ariwo
"aye dami loro" ni won lobinrin naa pe, to si bere sii pariwo kaakiri
adugbo naa, kawon eeyan too pe lee lori lati mo nnkan to n sele.
AWIKONKO
gbo pe, loju ese lawon araadugbo naa ti ya lo sile baba agbaya, eni odun
marundinlaadorin naa lati lo pariwo lee lori.
Kayeefi
loro naa je nigba ti won dele baba ti won dele baba ti won poruko e ni
Alosuposo bi iya miran naa tun se mu omo e, to je odun mewaa de pe baba naa ti
fipa ja ibale oun naa.
Okan
lara awon to gbo nipa isele naa ni won loo so pe ki won lo foro naa to awon
olopaa leti. Lesekese ni won ni oga olopaa ti won loro so fun, Ogbeni Makinde
Kayode ti lewaju awon olopaa to lo gbe baba naa nile.
Nigba
to n jeri sisele naa, Ogbeni Abimbola Oyeyemi to je agbenuso olopaa nipinle
Ogun so pe looto ni, atipe awon ti fesunkan an lesekese, eyi ti ko ni pe ti yoo
fi foju bale ejo.
O
so pe won ti gbe awon omo naa lo si jenera osibitu lati fo inu fun won, ki won
si toju eon lona to ye.
Oyeyemi
tun so pe, bakanna lawon tun ti rowo to awon akekoo ojewewe meta kan, ti won je
akekoo ileeko girama Ajagbe High School ti won fipa ba okan lara awon akekoo
won sun. o ni baba omo naa lo wa fejo sun awon olopaa.
Bee
lo wa fi kun oro e pe awon ko ni dawo duro lati maa gbogun ti iwa odaran
nipinle Ogun, nitori pe, alaafia awon araalu lo je awon logun.
No comments:
Post a Comment